HISTORY OF OUR PAST HEROES & HEROINES.
Yoruba past leaders contributed not only to the unity and development of the federal state of Nigeria, but also to the development of infrastuctures,education, health and social system of the whole yoruba tribe in general. Names of these leaders includes:
1. OBAFEMI JEREMIAH AWOLOWO
2. MACAULAY HERBERT
3. SAMUEL AJAYI CROWTHER
4. LADOKE AKINTOLA
5. FUNMILAYO RANSOME-KUTI
6. FRANCIS ADEKUNLE FAJUYI
*Ìtàn àwon àkoni wa tí ó ti kọjá lọ́kùnrin àti lóbìnrin*
Kìí se nínú ìṣọ̀kan àpapọ̀ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà nìkan ni àwọn adarí Yorùbá tí ó ti kọjá ti kópa, àti pẹ̀lú ìdàgbàsókè oun amáyédẹrùn, ètò ẹ̀kọ́, ètò ìlera àtí ètò àwùjọ gbogbo ẹ̀ya Yorùbá lápapọ̀. Orúkọ àwọn adarì wònyí ni:
1. OBAFEMI JEREMIAH AWOLOWO
2. MACAULAY HERBERT
3. SAMUEL AJAYI CROWTHER
4. LADOKE AKINTOLA
5. FUNMILAYO RANSOME-KUTI
6. FRANCIS ADEKUNLE FAJUYI